Ìjọba Ìpínlẹ̀ Enugu Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀gbìn Kòkó Lọ́pọ̀ Yanturu
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Enugu pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ olùdókóòwò aládàníi (White Rabbit Agro Litd) ti bẹ̀rẹ̀ ọ̀gbìn kòkó lọ́pọ̀ yanturu ni Ipinlẹ naa
Kọmísọ́nà Ètò Ọ̀gbìn Ní Ìpínlẹ̀ Enugu, Ọ̀gbẹ́ni Patrick Ubru ni ó…