Ọwọ́ Sìkún Àwọn Agbófinró Tẹ Arákùnrin Kan Tí Ó Pa Òògùn Olóró Mọ́ Sínú Bàtà
Àjọ tí ó ń gbógun ti lílo òògùn olóró ní orílẹ̀ èdè wa National Drug Law Enforcement Agency, NDLEA, ti fi ọwọ́ òfin mú agbénú òkùnkùn sebi kan, ẹni ọdún mẹ́tàdínlọ́gọ́ta (57), Lawal Lateef Oyenuga ní òpin ọ̀sẹ̀.…