Take a fresh look at your lifestyle.

Ìfẹ̀hónúhàn Lórí Ìtànkálẹ̀ Àrùn Covid-19 Gbòde Ní orílẹ̀ Èdè China

0 224

Àwọn ènìyàn orílẹ̀ èdè China ń fi àìdùnnú wọn hàn lórí ìtànkálẹ̀ àrùn covid-19, lẹ́yìn ìgbà tí ìjàm̀bá iná se ikú pa ènìyàn mẹ́wàá (10) ni ìlú Urumqi, olú ìlú Xinjiang ni ọjọ́bọ̀ (Sunday).

 

Àfiléde fi hàn pé àwọn ènìyàn jáde lọ́pọ̀ yanturu ní ọjọ́ ẹtì (Friday

) lẹ́yìn ìjàm̀bá iná tí o sẹlẹ̀ ní ọjọ́bọ̀ (Thursday).

 

Ní ìlú Shanghai ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn ti n péjọ ní alẹ́ ọjọ́ àbámẹ́ta (Saturday) fún ìkẹ́dùn àwọn tí ó pàdánù ẹ̀mí wọn, léyìí tí ó sì padà di ìfẹ̀hónúhàn ní ọjọ́ àìkú (Sunday).

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button