Ìjọba Nàìjíríà Sàgbékalẹ̀ Ètò Ìlera Jákè-jádò Orílẹ̀ Èdè
Ìjọba àpapọ̀ fi àrídájú rẹ̀ nípa ìsàgbékalẹ̀ ètò ìlera tí ó péye fún gbogbo mùtú-mùwà léde.
Mínísítà fún ètò ìlera, Dókítà Osagie Ehanire fi àrídájú náà hàn níbi àkójọpọ̀ kan nípa…