Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà Sàgbékalẹ̀ Ètò Ìlera Jákè-jádò Orílẹ̀ Èdè

0 147

Ìjọba àpapọ̀ fi àrídájú rẹ̀ nípa ìsàgbékalẹ̀  ètò ìlera tí ó péye fún gbogbo mùtú-mùwà léde.

 

Mínísítà fún ètò ìlera, Dókítà Osagie Ehanire fi àrídájú náà hàn níbi àkójọpọ̀ kan nípa ìsàgbéyẹ̀wò sí ètò ìlera, èyí tí ẹka ètò ìlera kan se agbátẹrù rẹ̀ ní ìlú Abuja.

 

Dókítà Ehanire sàpèjúwe ètò ìlera gẹ́gẹ́ bíi èyí tí o se pàtàkì kọjáa fífi ọwọ́ yẹpẹrẹ mú, Ó wá gbóríyìn fún ìjọba àpapọ̀ fún síṣe ètò ìlera tí ó múná-dóko fún mùtú-mùwà.

Leave A Reply

Your email address will not be published.