Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀dọ́mọdébìrin Ẹni Ọdún Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n Gba Oyè Ìmọ Ìjìnlẹ̀ PhD Nínú Ẹ̀kọ́ Ìsirò

Ọ̀dọ́mọdébìrin, Grace Ogwo ẹni Ọdún Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n gba oyè Ìmọ̀ Ìjìnlẹ̀ PhD Nínú Ẹ̀kó Ìsirò(Mathematics) bíotilẹjẹ wí pé, D7 àti C6 ni o ní nígbà tí o se Senior School Certificate Examination (WASSCE) ati NECO ninú Ẹ̀kó Ìsiro.…

Olórin Tó Tún Jẹ́ Òṣèré Ọmọ Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Falz Bẹ̀bẹ̀ Fún Àdúrà Lẹ́yìn Iṣẹ́ Abẹ

Ọmọ Nàìjíríà Olórin tó tún jẹ́ òṣèré, Folarin Falana tí wọ́n ń pè ní Falz ti bẹ̀bẹ̀ fún àdúrà àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí lẹ́yìn Isẹ́ abẹ tó se. Ó sọ èyí nípasẹ̀ Fídíò tó gbé jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára Instagram wipe " nǹkan tí òun ń…
button