Ikọ̀ Super Falcons Gbégbá Orókè Ní Ilẹ̀ Adúláwọ̀, Se Ipò Ẹ̀rìndínlógójì Lágbayé
Ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù obìnrin Nàìjíríà, Super Falcons dúró tipọ́n nípò wọn tíwọ́n wà nipa wíwà ní ipò kẹrìndínlógójì lágbayé.
Olùborí nígbà mésàn án ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ilẹ̀ Áfríkà dúró sí ipò yìí láti oṣù kẹta, ọdún 2024. Wọ́n sì tún wà…