Uganda: Àjọ WHO Ń Retí Abẹ́rẹ́ Èbólà Fún Ìdánwò
Abẹ́rẹ́ Ebola yóò dé sí Uganda laipẹ.
Olórí àjọ WHO Africa ti pàjàwìrì sọ wípé ìgbésẹ nlọ lọ́wọ́.
Láti ìgbà tí àrùn náà ti bù jáde ní ogúnjọ́ oṣù kẹsán, kòkòrò náà ti tàn káàkiri orílè-èdè náà tí ó sì ti fa ọwọ́ ètò ẹ̀kọ́…