Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdásílẹ̀ Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ní Yóò Fí Òpin Sí Rògbòdìyàn Ètò Ààbò – Gómìnà Sani

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna, Uba Sani, sọ pé ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ ní yóó fí òpin sí àwọn ìpèníjà ààbò tó ń wáyé ní gbogbo àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rin-dín-logójì (36) tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ‎ ‎ Gómìnà Uba, tó sọ èyí níbí ifọrọwanilẹnuwo kán ní…

Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà Ṣé ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Ilé-iṣẹ́ Ológun Israel

Ilé-iṣẹ́ tí Ààbò tí tún fí hàn pé ìjọba Nàìjíríà ìtẹ̀síwájú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Ilé-iṣẹ́ ológun rẹ̀ pẹlú tí Orílẹ̀-èdè Israel. ‎ ‎ Akọwe àgbà tí Ilé-iṣẹ́ ológun náà, Gabriel Aduda, tó pàdé pẹ̀lú Aṣojú Israeli sí Nàìjíríà, Michael Freeman,…

Ìgbákejì Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Yóò Ṣé Ònígbọwọ́ Awọ́n Ọ́ọ̀dúnrún Ní Ilé-Ẹ̀kọ́ Gíga

Ìgbákejì Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Agba, Barau Jibril, tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ètò ilé-ẹ̀kọ́ fún àwọn Ọ́ọ̀dúnrún ọmọ abínibí Ìpínlẹ̀ Kano sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga Nàìjíríà lábẹ́ àbójútó "Barau Jibril Foundation." ‎ ‎ O sọ pé sikọlaṣipu…

Ìgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pé Fún Àlàáfíà, Ìfarádà Òṣèlú Ní Ìpínlẹ̀ Kano ‎

Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kashim Shettima tí ké sí àwọn Olóṣèlú ní ìpínlẹ̀ Kano, Ìwọ̀-oòrùn Àríwá Nàìjíríà láti gbá àlàáfíà láàyè kó jọba ní Ìpínlẹ̀ náà. ‎ ‎ Shettima ṣé ìpè yìí l'àkókò tó ṣé àbẹwò ìtùnú sí ìdílé Galadinma Kano,…

TETFUND Gbóríyìn Fún Ètò-Ẹkọ Àti Ètò Ìdàgbàsókè Tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara

‎ Ọkàn nínú àwọn Ọmọ ẹgbẹ́ ìnáwó ètò ẹ̀kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga (Tertiary Education Trust Fund TETFUND) tó ń sójú agbègbè àárín gbùngbùn àríwá, Engineer Nurudeen Adeyemi Balogun ṣé àbẹwò sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara tó tún jẹ́ Alága Ìgbimọ àwọn Gómìnà…

Irọ́ Lásán Ní Ìròyìn Tí Àwọn Agbesunmọmi Tó Ń Lọ́ Ní Ìpínlẹ̀ Kwara – Ilé-iṣẹ́ Ọlọ́pàá

Ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá ní Ìpínlẹ̀ Kwara tí takò àtẹ̀jáde kán tó níí ṣé pẹ̀lú ẹsùn ìkọlù kán tí wọ́n ní àwọn agbesunmọmi kán tí orúkọ wọ́n njẹ́ Mahmuda láàrin ìjọba ìbílẹ̀ Kaiama ati Baruten ní ìpínlẹ̀ Kwara. ‎ ‎ Nínú àlàyé kán látí ẹnu Aláṣẹ…

Aṣáájú Nàìjíríà Gbá Àkọlé Àṣà Ìbílẹ̀ Tó Gíga Jùlọ Ní Akwa Ibom ‎

Ìgbìmọ̀ Àwọn Alàkóso ìbílẹ̀ tí Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom tí ṣé ọla fún Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu pẹ̀lú àkọlé tó gá jùlọ tí "Otuekong," èyí tó ṣàfihàn Ààrẹ gẹ́gẹ́bí Alàkóso àgbà ní Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom. ‎ ‎ Ibù-ọlá fún Ààrẹ náà ló wáyé ní ọjọ́ Ẹtì ní…

Isreal, Palestine Ṣé Pàṣípààrọ̀ Àwọn Òkú Àti Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n L’ójúnà Látí Fopin Sí Ogún

Isreal àti Palestine tí ṣé pàṣípààrọ̀ àwọn àpótí Òkú mẹ́rin kán tó jẹ́ tí àwọn ọmọ Israel tó kú sínú túbú, bí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Palẹ́síténì tí wọ́n tí mọ́ ẹ̀wọ̀n àti àwọn tó wá ní atimọle tí gbá itu sílẹ ní Gaza àti àwọn tí 'West Bank'…
button