Take a fresh look at your lifestyle.

TETFUND Gbóríyìn Fún Ètò-Ẹkọ Àti Ètò Ìdàgbàsókè Tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara

Lekan Orenuga

83

Ọkàn nínú àwọn Ọmọ ẹgbẹ́ ìnáwó ètò ẹ̀kọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga (Tertiary Education Trust Fund TETFUND) tó ń sójú agbègbè àárín gbùngbùn àríwá, Engineer Nurudeen Adeyemi Balogun ṣé àbẹwò sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara tó tún jẹ́ Alága Ìgbimọ àwọn Gómìnà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mallam AbdulRahman AbdulRazaq, ni Ile Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara, Ilorin.

‎ Àbẹwò náà, eyiti o wáyé lẹyìn ìpàdé Ìgbìmọ̀ TETFUND túntún náà, yóò dojú kọ ìmúláradá ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin Àjọ tí ìjọba àpapọ̀ àti Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ní àgbègbè ètò-ẹ̀kọ́, àwọn àmáyédẹrùn, àti Imúdára àwọn ọdọ.

‎ L’akoko àbẹwò náà, Nurudeen Adeyemi yìn Gómìnà AbdulRazaq fún àwọn ètò ìlọsíwájú nínú ti ìṣàkóso rẹ̀ lórí ìdàgbàsókè òun àmáyédẹrùn àti pàápàá ètò ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè àwọn ènìyàn Ìpínlẹ̀ náà.

Comments are closed.

button