Orílẹ̀-èdè Faransé Kìlọ Fún Iran Lórí Fífi Drone Ránṣẹ́ Sí Russia
Ààrẹ Faransé Emmanuel Macron tí kìlọ fún Ààrẹ Iran Ebrahim Raisi nípa ìpàdábọ̀ àwọn ọkọ ìjà ofurufu (Drone) rẹ̀ tó fí ń ránṣẹ́ sí Russia.
Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ Faransé náà sọ nínú àlàyé kàn pé Ààrẹ Macron rọ́ Ààrẹ Iran látí dẹkùn àtìlẹ́yìn tó…