Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbákejì Ààrẹ Shettima Kẹ́dun Ikú Ọ̀jọ̀gbọ́n Ajewole

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 279

Ìgbákejì Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sen. Kashim Shettima tí kẹ́dun pẹ̀lú ẹbí olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Opeyemi Ajowole. Ọ̀jọ̀gbọ́n olókìkí tí Àwùjọ àtí Àyíká, tí wọ́n tá ní ìbọ́n ní alẹ́ Ọjọ́ Ajé ní Ibadan nípasẹ̀ àwọn apànìyàn tí a kó tí mọ́.

Ìgbákejì Ààrẹ sọ èyí nínú Ìfiránṣẹ́ rẹ̀ sí ẹ̀bí olóògbé náà ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun, tó ń ṣàlàyé ìyàlẹ́nu lórí pípa tí Ọ̀jọ̀gbọ́n náà.

Tún kà nípa:Igbákejì ààrẹ Shettima bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́

Nígbà tí Ìgbákejì Ààrẹ n kẹ́dùn pẹ̀lú ìdílé Olóògbé Ọ̀jọ̀gbọ́n Ajewole, àti Fásítì Ibadan Master Class tí 1990, Ìgbákejì Ààrẹ bú ẹ̀nú àtẹ́ lú ìpànìyàn burúkú náà àti ikú airotẹlẹ rẹ̀, ní ọjọ́ diẹ lẹ́yìn tí Ọ̀jọ̀gbọ́n náà kí òun kú oríire fún ìbura rẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button