Ààrẹ Tinubu Gbóríyìn Fún Àwọn Àkitiyan Tí Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Aboh Ṣé Ní Iṣẹ́ AI
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí gbóríyìn fún ọ̀gbẹ́ni Abel Aboh, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, fún gbígbé ògo orílẹ̀-èdè náà ga lórí ìpele àgbáyé ní ẹ̀ka ìmọ̀ ọgbọ́n AI.
Ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ alamọdaju òye AI tí àrà ìlú Gẹ̀ẹ́sì ní wọ́n yán láìpẹ́ yíì sínú Ìgbìmọ̀ Ilé-iṣẹ́ Data Lab Innovation Centre, Scotland, United Kingdom.
Nínú Ìfiránṣẹ́ kàn, Ààrẹ Tinubu ṣé àkíyèsí pẹ̀lú ìgbéraga àti ifọkanbalẹ sí àwọn àṣeyọrí ọ̀jọ̀gbọ́n tí Aboh ní United Kingdom àtí bí ìmọ̀ rẹ̀ àti ipò Àdári túntún rẹ̀ ṣé àfihàn ìgbésẹ pàtàkì nínú àwọn ìgbìyànjú ilé-iṣẹ́ nínú data Scotland àtí àgbàrá AI.
Ìmọ̀ òye, ìmọ̀-ẹ̀rọ́ data àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ́, yóò gbá ìpele àárín gbùngbùn ìmọ ẹ̀rọ́ túntún ní àgbáyé, gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ Nàìjíríà ṣé sọ.
Tún kà nípa:Ààrẹ Tinubu Ń Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwon Olórí Ààbò
Ó fí kún pé ìṣàkóso rẹ̀ yóò ṣé ìmọ̀-ẹ̀rọ́ ní pàtàkì imọ-ẹrọ l’ojuna látí pèsè ọjọ́ ọlá tó dára fún àwọn ọdọ Nàìjíríà tí yóò tún máa Aboh gẹ́gẹ́ bí awokọṣe.
Leave a Reply