Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè South Africa Yóò Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Ààrẹ America Lórí Rògbòdìyàn Abẹ́lé

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè South Africa, Cyril Ramaphosa àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè America Donald Trump tí ṣètò láti pàdé ní Ilè Ìjọba America ní ọsẹ tí n bọ̀ lẹ́yìn àwọn ẹsùn tí Trump pé wọ́n ń ṣé ẹlẹyamẹya láàrín àwon dúdú áti fúnfún ní Orílẹ̀-ẹ̀dẹ̀ dúdú…

Nàìjíríà Fìdí Ìfaramọ́ Rẹ̀ Múlẹ̀ Fún Ètò Ẹ̀kọ́ Ọ̀dọ́mọbìnrin ‎

Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Suwaiba Ahmad, tí tún ṣé ìdánilójú ìfaramọ́ tí ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látí fí àgbàrá fún àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin Nàìjíríà nípasẹ ìsopọ̀, ifọkanbalẹ àti ètò ẹ̀kọ́ tó dídára. ‎ ‎ O ṣé ìdánilójú…

Gómìnà Yusuf Fọwọ́sí Gbígba Àwọn Olùkọ́ Ẹgbẹ̀rún Mẹ́rin ‎

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano ní Àríwá Ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà, Abba Kabir Yusuf, tí pàṣẹ fún Ilé-iṣẹ́ tí Ẹ̀kọ́ ní ìpínlẹ̀ náà ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Ìgbìmọ̀ tí Ẹ̀kọ́ Ìpìlẹ̀ tí ìpínlẹ̀ náà (SUBEB) látí bẹ̀rẹ ìlànà tí gbígbà ọgọọgọrùn àwọn olùkọ́ tí…

Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ Nàìjíríà Buwọ́lù Tírílíọ̀nù Kán Lè Díẹ̀ Fún Àwọn Iṣẹ́ Àmáyédẹrùn Tí Orílẹ̀-èdè

Ìgbìmọ̀ àwọn Aláṣẹ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (FEC) tí fọwọ́sí tírílíọ̀nù kán lè díẹ̀ Náírà (N1.202) fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe àmáyédẹrùn orílẹ̀-èdè pàtàkì bí iná mọna-mọna, Pápákọ́ Òfurufú, àti àwọn iṣẹ́ òpópó-ònà tí nlọ lọwọ́. ‎ ‎ Ìgbésẹ pàtàkì…

Mínísítà Ìròyìn Pé Fún Ọnà Látí Wá  Ojútùú Sí Ìpèníjà Ààbò

Mínísítà fún Ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, sọ pé ọnà látí wá ojútùú sí ìpèníjà Ààbò èyí tí kó nilo ìgbìyànjú púpọ̀ jú ìfẹ láti ọdọ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sí ilú wọ́n. ‎ ‎ Ọ̀gbẹ́ni Idris, ẹni tó sọ èyí ní…
button