Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Fún Nàìjíríà Ní Ẹgbẹ̀rún Lọnà Àádọ́run Dọla
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Améríkà ló fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní owó ẹbùn ẹgbẹ̀rún lọnà àádọ́run dọla ($90,000) latari àdéhùn àjọṣepọ̀ lórí ìtọ́jú Oun-ìní Àṣà tí ìnáwó Ọdún 2023, fún ìdáàbòbò àwọn òun-ìní àti òun ọ̀ṣọ́ Nok.
Ẹbùn owó náà ní…