Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí pàdà sí Olú-ìlú ní Abuja lẹ́yìn ìpàdé àwọn Olórí Orílẹ-èdè ní ilẹ̀ Áfíríkà ní Dar es Salaam, Tanzania.
Ní irọlẹ ọjọ́ Ìṣẹgun ní ọkọ òfurufú tí Ààrẹ balẹ̀ sí ilé-iṣẹ́ ọkọ Òfurufú tí Nnamdi Azikiwe ní Abuja ní nnkan bíi ago mẹjọ kú ogún iṣẹ́jú.
Femi Gbajabiamila, olórí àwon òṣìṣẹ́ Ààrẹ, Mínísítà tí Ìpínlẹ̀ fún Ìdáàbòbò, Bello Matawalle, àti Olùdámọ̀ràn Ààrẹ lórí Ààbò Orílẹ̀-èdè, Nuhu Ribadu, atí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba gíga mìíràn ló tẹwọgbà Ààrẹ ní papakọ̀ Òfurufú ní Abuja
Nínú Àpéjọ ọlọjọ méjì, Ààrẹ Tinubu tún ṣé ìlérí rẹ̀ láti jẹ́ kí èpò rọbi lilo dí òun ìrọ̀rùn fún àwọn olùgbé orílẹ-èdè náà.
Comments are closed.