Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpànìyàn: Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kẹdun Pẹ̀lú Ìjọba Ìpínlẹ̀ Benue

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí bú ẹnu àtẹ lù ikọlù tó ṣẹṣẹ wáyé ní ìpínlẹ̀ Benue. Nínú ọrọ rẹ̀, Ààrẹ sọ pé kò sí itẹwọgbà fún ẹnikẹ́ni láti gbà ẹmi ẹnìkejì yálà darandaran ní tàbí àgbẹ̀. “Ẹnikẹ́ni kò gbọ́dọ̀ kọlù ẹnikẹ́jì nítorí ọ̀nà…

Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Fèsì Sì Ìdájọ́ Ilé-Ẹ̀jọ́ lórí Ẹjọ́ Kanu

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé, àwọn yóò ṣé àṣàyàn àwọn ìlànà tó dìrọ̀ mọ̀ ìdájọ ṣiṣi olórí àwọn Indigenous peoples of Biafra (IPOB) ọgbẹni Nnamdi Kanu sílẹ̀ tí ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ṣé ní Ọjọ́bọ̀. Agbẹjọro ijọba ati Mínísítà fún Ìdájọ́,…

Ẹgbẹ́ Olukọni Ìlé-ẹ̀kọ́ Gíga Fagilé Iyanṣẹlòdì Wọ́n

Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Ilé-ẹjọ́ gíga (ASUU) tí Fagilé iyánṣẹ̀lòdì tí olóṣù mẹjọ rẹ̀ pẹlú majẹmu, ọkàn nínú àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ Aláṣẹ ti ẹgbẹ́ náà sọ fún àwọn oníròyìn ní kùtù òwúrọ̀ ọjọ́ Ẹtì. Ẹgbẹ́ náà pinnu láti dá Ìdásẹsílẹ̀ náà dúró níbí ìpàdé…
button