Hong Kong Ṣé Tán Láti F’ayé Gbà Àkójọpọ̀ Àwọn Àrà Ìlú ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉÌRÒYÌN ÌLERAKÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN By Lekan Orenuga On Oct 18, 2022 0 368 Share Ìlú Hong Kong yóò ṣé ìgbàláàyè fún àwọn àrà ìlú tí àpéjọ wọn kojú méjìlá lọ láti pejọ ní gbángba láti Ọjọ́bọ̀. Àpéjọ ènìyàn mẹrin ló wà lọwọlọwọ bí ijọba ṣé ń tẹsíwájú lórí yíyọ àwọn òfin tó dé COVID-19. Lekan Orenuga 0 368 Share FacebookTwitterWhatsAppEmailLinkedinTelegram
Leave a Reply