Ní iṣẹju kọọkan ní orílẹ̀-èdè Somalia ní a ń gbà Ọmọde kàn fún ìtọ́jú àìjẹun kánù bí ọgbẹlẹ tó lágbára ṣé ń ṣẹlẹ̀ làti fà ikù àwọn ọmọdé tí kò ṣẹlẹ̀ rí ní ọgọrùn ọdún, agbẹnusọ kàn fún UNICEF sọ ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun.
“Ipò tí orílẹ̀-èdè Somalia wà yíì buruju tí ọdún 2011,” agbẹnusọ náà sọ fún àpéjọ kàn ní Geneva, nígbàtí iyán tí pá àwọn ènìyàn tí ìyè wọ́n kò kéré sí ẹgbẹ̀rún ìgbálélàádọ̀tà (250,000) ní orílẹ̀-èdè Adúláwọ̀ náà.
Lekan Orenuga
Leave a Reply