Take a fresh look at your lifestyle.

Àṣeparí ìdìbò gómìnà : Alága INEC rọ àwọn òṣìṣẹ́ elétò ìdìbò láti ṣe iṣẹ́ wọn…

Alága ìgbìmọ̀ olómìnira tó ń mójútó ètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè, INEC, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu ri rọ àwọn òṣìṣẹ́ ìgbìmọ̀ náà láti ṣàfihàn bí wọ́n ṣe nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè wọn àti ìmọṣẹ́ wọn bíi iṣẹ́. O pe…

Adamawa yóò fún àwọn ọmọ bìnrin tó fẹ́ẹ̀ tó irínwó ẹgbẹ̀rún ní abẹ́rẹ́ àjẹsára láti…

Ilé–iṣẹ́ tó ń mójútó ìdàgbàsóke ètò ìlera abẹ́lé ní ìpínlẹ̀ Adamawa, ti sọ pé òun gbìmọ̀ láti fún àwọn ọmọ bìnrin láti ọdún mẹ́sàn án sí ọdún mẹ́rìnlá tó fẹ́ẹ̀ tó irínwó ẹgbẹ̀rún ní abẹ́rẹ́ àjẹsára…

Jẹjẹrẹ ẹnu ilé-ọmọ: Irínwó àwọn obìnrin ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun yóò ṣe àyẹ̀wò

Ìjọba ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ilé ìfowópamọ́ àgbáyé, ti ṣe àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ fún Jẹjẹrẹ ẹnu ilé-ọmọ àti ọyàn fún àwọn obìnrin tí ó ju irínwó lọ, ní àwọn agbègbè kan ní ìpínlẹ̀ náà. Ayẹwo naa wa…

Ìpínlẹ̀ Sokoto : Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ jáde fi oyè yẹ́ alákóso olùdásílẹ̀ sí, àwọn…

Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ jáde ilé-èkọ́ gíga Fáfítì Usman Danfodio ti fi oyè yẹ́ alákóso olùdásílẹ̀, Ọ̀jọ̀gbọ́n Sai’du Galaganchi àti àwọn tí wọ́n wá lẹ́yìn rẹ̀ si. Awọn miiran ti wọn tun foye yẹ si ni, ọmọ orilẹ-ede ti…

Ìjàm̀bá Ọkọ̀ òfurufú: Kòsí ìpalára tó le – Ìgbìmọ̀ Ìṣèwáádí

Ilé-iṣẹ́ tí ń ṣe ìwádìí ààbò ní Nàìjíríà (NSIB), ti ṣàlàyè pé kò sí ìpalára kan dàbí alárà nínú ìjàm̀bá tó wáyé pẹ̀lú ọkọ̀ òfurufú  HS 125, ti orílẹ̀-èdè, tí nọ́ḿbà ìdánimọ̀ rẹ̀ jẹ́ 5N-AMM, tí…

Ilé ìgbìmọ̀ Nàìjíríà yóò ṣe ìpàdé pàjáwìrì ní ọjọ́ Ajé

Ilé ìgbìmọ̀ Nàìjíríà yóò ṣe ìpàdé pàjáwìrì ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹfà, osù kọkànlá 2023, láti buwọ́lu ìbò àti àwọn ababọ ètò tí wọ́n ṣe níbi ìjókóo Ọjọ́ọ́rú tó kọjá. Ile igbimọ n gbero lati buwọlu ijabọ…
button