Take a fresh look at your lifestyle.

Irin-iṣẹ́ ológun: Nàìjíríà yóò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Amẹ́ríkà

Ilé-isẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń mójútó ètò ààbò ti ń jumọsọrọ pẹlu ile-iṣẹ ọkọ ofurufu ti Gusu Ariwa (NEANY), lori ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ Amẹ́ríkà àti Àjọ tó ń mójútó ààbo ilé-iṣẹ́ ní Nàìjíríà (DICON).…

Ààrẹ Tinubu ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú adarí orílẹ̀-èdè nígbà kan rí, Buhari ní ọdún…

Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Ahmed Tinubu ti ṣàpèjúwe ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí náà Muhammadu Buhari, bíí àwòkọ́ṣe ìfaradà, ìfọkànsìn, ẹni tí ó fẹ́ràn orílẹ̀-èdè rẹ̀ àti tí ó tún lọ́kàn tó mọ́ sí orílẹ̀-èdè, bí ó ṣe ń…

Akọ̀wé gbogbogbòò rọ àwọn Dókítà, òṣìṣẹ́ elétò ilérà láti dúró sí Nàìjíríà

Akọ̀wé gbogbogbòò, Ilé iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí ń mójútó ètò ààbò, Dókítà Ibrahim Abubakar Kana, ti ṣàlàyé pé ìjọba àpapọ̀ ń sa gbogbo ipá rẹ̀ láti ṣàtúnṣe lórí abala ètò ìlera ní Nàìjíríà, tí ó ṣì…

UAE yóò pèsè ibùdó ìṣàgbékalẹ̀ ìrànlọ́wọ́ jákèjádò Nàìjíríà

Ìjọba Nàìjíríà ti rí ìrànlọ́wọ́ gbà láti ọ̀dọ̀ United Arab Emirates (UAE) ,fún ìṣàgbékalẹ̀ ibùdó tí wọn yóò ti máa ṣàánú jákèjádò orílẹ̀-èdè láti pèsè ìrànlọ́wọ́ fún àwọn olùfaragbà àjálù…

Àwọn Mínísítà Áfíríkà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè mẹ́ta gbìmọ̀ àjọṣepọ̀

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè ti Burkina Faso, Guinea àti Mali, tí ológun ń ṣe ìjọba rẹ̀, ti gbìmọ̀ àjọṣepọ̀ tí yóò pèsè káràkátà àti ìkojú àìláábò ní agbègbè, wọ́n sọ èyí gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rọ̀ àjọsọ nígbà…

COP28: Ààrẹ Pè fún ìnáwó tó tọ́ láti ran àwọn orílẹ̀-èdè tó ní ìpalára lọ́wọ́.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè South Africa ti rọ àwọn adarí lágbàáyé , tí wọ́n kórajọ fún COP28, láti ran àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kojú ìpalára làásìgbò ojú ọjọ́ lọ́nà tó pọ̀ ju bó ṣe yẹ lọ. Ninu itan, awọn orilẹ-ede to n…
button