Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà, Bulgaria yóò túnbọ̀ fìdí ètò ẹ̀kọ́ ààrin wọn múlẹ̀ si

Mínísítà fún ètò Ẹ̀kọ́, Ọ̀jọ̀gbọ́n Tahir Mamman, ti sọ pé Nàìjíríà ti ṣetán láti túnbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀ pẹ̀lú orílẹ̀-èdè Bulgaria múlẹ̀ ní abala ètò ẹ̀kọ́. Minisita naa wa pinnu pe wọn yoo ṣe eto isọdọtun adehun…

Ẹgbẹ̀rún ènìyàn sá àsálà bí àwọn ọmọ ogun Israeli ṣe súnmọ́ Gúsù Gaza

Bí ìjà náà ṣe ń gbilẹ̀ si ní Gúsù ìlú Gaza tí Khan Yunis, ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ Palestine ń gbéra súnmọ́ Rafah lẹ́gbẹ́ẹ ààlà Egypt, tí wọ́n sì ń gbé àwọn nǹkan wọn tí wọ́n le gbé. Awọn ọmọ ogun Israeli ti paṣẹ…

Mínísítà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ pè fún ìṣọ̀kan, tí ó sì ní kò sí ohun tó jọ…

Mínísítà Nàìjíríà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti àfiyé lórílẹ̀-èdè, Mohammed Idris, ti pè fún ìṣọ̀kan tí ó sì ní kò sí ohun tó jọ àìsedéédé àlàyé lórí ìṣàkóso orílẹ̀-èdè. Ninu alaye iroyin kan…

Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ nígbà kan rí gba oríyìn fún ìyípadà tó dé bá àwọn…

Mínísítà Nàìjíríà fún ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ọrọ̀-Ajé orí Ayélujára nígbà kan rí , Ọ̀jọ̀gbọ́n Isa Ali Pantami, ti gba oríyìn fún ipa adarí àti ìṣèdásílẹ̀ àwọn ìlànà lórí ìdàgbàsókè ayélujára…

Àwọn ọmọdé tí kò sí ní ilé ìwé mọ́: Nasarawa fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Nasarawa ti sọ pé òhun ti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn òbí tí kò ní owó tó tó láti rán àwọn ọmọ wọn lọ sí ilé ìwé ní ìpínlẹ̀ náà. Kọmiṣọna ipinlẹ…
button