Take a fresh look at your lifestyle.

A ó pèsè ìrànwọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn olùgbọ́ won láti le ní ìgbésí ayé…

Ní ọdún tó kọjá, àwọn yàrá ìròyìn àádọ́jọ  kópa nínú ìpolongo Ọjọ́ àyájọ́  ìròyìn Àgbáyé, tí Àpèjọ Àwọn Olóòtú Àgbáyé àti ìjọ akọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè Kánádà gbékalẹ̀. Ó jẹ́ ara akitiyan  …

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ FEC fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì Náírà…

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì fún píparí àwọn  iṣẹ́ àkànṣe òpópónà ní ìpínlẹ̀ márùn – ún jákàjádò orílẹ̀-èdè. Minisita fun Iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashola…

Igbákejì ààrẹ,Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò polongo ìtẹ̀sìwájú lórí Ìṣòwò iṣẹ́ àkànṣe…

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé àwọn akitiyan ti ó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti fi òpin sí ìdàgbàsókè àwọn iṣẹ́ àkànṣe gáásì ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lòdì sí àwọn ìpilẹ̀…

Ìkọlù NDA : Alákóso ṣàgbékalẹ̀ ìjábọ̀ fún ilé Ìgbìmọ̀

Alákóso Ilé -ẹ̀kọ́ gíga ti Ìdàábòbò Nàìjíríà, NDA, ti tún tẹnumọ pé  ìgbìyànjú ń lọ lọ́wọ́ láti gba ọmọ -ogun tí wọ́n jí gbé ní ilé -iṣẹ́ náà ní Oṣù Kẹjọ àti láti  ríi dájú pé irúu ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ kò…

Covid-19:Àwọn ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún- dín- lọ́́rìn- lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn…

Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣàkóso àjàkalẹ̀ ààrùn NCDC ti kéde pé ènìyàn mẹ́ẹ̀dógún-dín –lọ́rìn-lé-lọ́ọ̀dúnrún míràn àn tún ti ní ààrùn covid tí méjọ sì jẹ́pè ọlọ́run ní ọjọ́ kejìlá oṣù kẹsàn-án,ọdún 2021.…
button