Take a fresh look at your lifestyle.

Ààre Bùhárí yóò ṣe àbẹ̀wò sí ìpínlẹ̀ Ògùn ní ọjọ́bọ̀

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí yóò ṣàbẹ̀wò sí ìpínlẹ̀ Ògùn, gúúsù ìwọ oòrùn ní ọjọ́bọ̀ ,ọjọ́ kẹtàlá,ọṣù kínní,ọdún 2022. Lakoko abẹwo naa, Aarẹ Buhari yoo ṣe ifilọlẹ awọn iṣẹ akanṣe kan ti…

Àwọn ọmọ ogun jẹ́ ààmi ìṣọ̀kan orílẹ̀-èdè- VP Ọ̀sínbàjò

Igbákejì Ààre orílè-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé Àwọn ológun  Nàìjíríà jẹ́ ààmì ẹ̀mí àtúnṣe orílẹ̀-èdè, ìsọ̀kan àti agbára ní onírúurú láti oríi ogun abẹ́lé sí ìgbógun ti àwọn…

Àwọn ọlọ́pàá Kẹnya Mú àwọn tí wọ́n furasí mẹ́jọ kan lórí ìkọlù Lámù

Àwọn ọlọ́pàá Kẹnya ti mú ènìyàn mẹ́jọ tí ó níṣe pẹ̀lú ìkọlù ọjọ́ ajé ní agbègbè Lámù ní etíkùn Kẹnya, nínú èyítí  ènìyàn mẹ́fà pàdánù ẹ̀mí wọn, tí wọ́n sì jó ilé níná. Awọn ọlọpa ti mu awọn mẹrin…

Àwọn Gómìnà Gúúsù Iwọ̀-Oòrùn bẹnu àtẹ́ lu àìkànisí AGF, IGP sí Gómìnà Sanwo-Olu

Àpéjọ àwọn gómìnà Gúúsù iwọ̀ - oòrùn ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí ọ̀gá àgbà adájọ́ àpapọ̀ àti Mínísítà fún Ìdájọ́, Abubakar Malami, SAN, àti ọ̀gá-Àgbà àwọn ọlọ́pàá, IGP Usman Baba, 'àìkanisí tí ògá ọlọ́pàá…

Àjọ NGO Fún Àwon Aláìní,ilé Ìjọsìn àti Àwon Olórí Agbègbè Ní Èbònyì nílé

Àjọ tí kìí ṣe tìjọba, NGO , tí a mọ̀ sí Ebele àti AnyiChucks Foundation ti  ṣàfihàn àti ìṣètọrẹ ilé mẹ́tàlé- lógún kan fún  Àwọn Aláìní, Àwọn ilé ìjọsìn àti àwọn aṣaájú agbègbè láti pèsè ààbò tó jọjú…

Àṣeyọrí ètò: Olùdarí àgbà fún NYSC gbóríyìn fún Àwọn Òṣìṣẹ́

Olùdarí Gbogbogbòò fún àgùnbánirọ̀ (NYSC), ajagun Shuaibu Ibrahim ti gbóríyìn fún àwọn òṣìṣẹ́ lórí àwọn ipa pàtàkì tí wọn kó nínú  àṣeyọrí tí ìṣàkóso  ìjọba rẹ̀ ti ṣe títí di àsìkò yìí,ó wá rọ̀ wọ́n…

Nàìjíríà bẹ̀rẹ̀ ojúṣe rẹ̀ gẹ́gẹ́ Bí Akọ̀wé D- 8 Gbogbogboọò Ní Tọ́kì

Asojú Nàìjíríà sí orílẹ̀-èdè Tọ́kì, Ísíákà Abdulqadir Imam ti gba iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Akọ̀wé Àgbà ti D-8 àjọ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ọrọ̀-ajé  ní Istanbul, Tọ́kì. Gẹ́gẹ́ bí àtẹ̀jáde Abdullahi Tukur ti ilé iṣẹ́ ìjọba ilẹ̀ òkèèrè…
button