Ise agbe nise ile wa
Ààrẹ ẹgbẹ́ awon oloja lorile-ede Naijiria, Alhaji Mustafa Ahmadu, ti rọ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti mu iṣẹ́ àgbẹ̀ lokúnkundun, kí wọ́n sì padà sẹ́nu iṣẹ́ àgbẹ̀, nitori pé kí orílẹ̀-èdè kankan to le bo ara re yo, tabi ṣaṣeyọri lori…