Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ àwọn mínísítà Nàìjíríà buwọ́lù iye owó tó tó bílíọ́nù méjì Náírà…

Ìgbìmọ̀ Aláse ìjọba àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tó tó bílíọ́nù méjì Náírà  fún àwọn àdéhùn márùn ún ní Ilé -ẹkọ́ gíga fáfítì Nnamdi Azikiwe, Awka, Ìpínlẹ̀ Anambra. Ibuwọlu naa waye  nibi ipade minisita ni…

Covid-19: Àwọn ènìyàn mèje -dín- ní -okòó-lé-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta míràn tún ti ní ààrùn…

Ní ọjọ́ kọkànlé-lógún oṣù kẹsàn án,ọdún 2021, ènìyàn mẹ́tàlá –lé –lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta míràn ló tún ti kó ààrùn covid, tí ènìyàn mẹ́ta sì jọ́lọ́run nípè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,gẹ́gẹ́ bíi ilé iṣẹ́ tó ń…

Igbákejì ààrẹ Òsínbàjò ń darí àpèjọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Igbákejì ààrẹ Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò ń darí àpèjọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ lórí ayélujára ní ilé-ìlú . Osinbajo n ṣe alaga ipade naa nitori pe  aarẹ Muhammadu Buhari  wa ni New York, Orilẹ- ede Amẹrika, lati kopa ninu…

A ó pèsè ìrànwọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn olùgbọ́ won láti le ní ìgbésí ayé…

Ní ọdún tó kọjá, àwọn yàrá ìròyìn àádọ́jọ  kópa nínú ìpolongo Ọjọ́ àyájọ́  ìròyìn Àgbáyé, tí Àpèjọ Àwọn Olóòtú Àgbáyé àti ìjọ akọ̀ròyìn ti orílẹ̀-èdè Kánádà gbékalẹ̀. Ó jẹ́ ara akitiyan  …

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ FEC fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì Náírà…

Ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀ ti fọwọ́sí iye owó tótó bílíọ̀nù méjìdín-lógójì fún píparí àwọn  iṣẹ́ àkànṣe òpópónà ní ìpínlẹ̀ márùn – ún jákàjádò orílẹ̀-èdè. Minisita fun Iṣẹ ati Ibugbe, Babatunde Fashola…

Igbákejì ààrẹ,Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀sínbàjò polongo ìtẹ̀sìwájú lórí Ìṣòwò iṣẹ́ àkànṣe…

Igbákejì ààrẹ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé àwọn akitiyan ti ó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́ láti fi òpin sí ìdàgbàsókè àwọn iṣẹ́ àkànṣe gáásì ní ilẹ̀ adúláwọ̀ lòdì sí àwọn ìpilẹ̀…

Ìkọlù NDA : Alákóso ṣàgbékalẹ̀ ìjábọ̀ fún ilé Ìgbìmọ̀

Alákóso Ilé -ẹ̀kọ́ gíga ti Ìdàábòbò Nàìjíríà, NDA, ti tún tẹnumọ pé  ìgbìyànjú ń lọ lọ́wọ́ láti gba ọmọ -ogun tí wọ́n jí gbé ní ilé -iṣẹ́ náà ní Oṣù Kẹjọ àti láti  ríi dájú pé irúu ìṣẹ̀lẹ̀ bẹ́ẹ̀ kò…
button