Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn mèje -dín- ní -okòó-lé-ní-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta míràn tún ti ní ààrùn covid

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

111

Ní ọjọ́ kọkànlé-lógún oṣù kẹsàn án,ọdún 2021, ènìyàn mẹ́tàlá –lé –lẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀ta míràn ló tún ti kó ààrùn covid, tí ènìyàn mẹ́ta sì jọ́lọ́run nípè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,gẹ́gẹ́ bíi ilé iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ní Nàìjíríà (NCDC) ) ṣe sọ ní wẹ́ẹ́bù rẹ̀.

Lọwọlọwọ bayii, eniyan ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún le ni ọ̀kẹ́ mẹ̀wá o din ni ẹ̀rin din ni ọgọ́rùn lo ti ni aarun naa,

Eniyan ẹgbẹ́rún- le –ni- ọ̀kẹ́ -mẹ̀sán- abo- o- le –ni- ọ́rin-din-lẹwá -lelọ́ọ̀dúnrún ti gba iwosan ti

ẹ̀rin-din-ni-ojì din ni ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ẹ̀rinlá eniyan si ti jẹpẹ oluwa ni ipinlẹ mẹrindin-logoji ati olu-ilu.

Awọn eniyan mèje din ni okòó-le-ni-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta yii jẹyọ ni awọn ipinlẹ mẹẹdogun –Lagos (èjì le ni àádọ́je)

Olu-ilu (ọgọrin ),Rivers (aadọrin ),Kaduna (mẹtale-logoji), Ẹdo (ogoji ), Ondo (mejile-lọgbọn ), Delta (mẹtale-logun ),Akwa Ibom (mọkanle-logun), Kwara (mẹrindin-logun ),Gombe (mejila), Anambra (mẹsan an ),Benue (mẹsan an ), Kano (meje), Ọyọ (mẹfa ), Borno (mẹta ),Bayelsa (meji ), Katsina (meji) ,Ogun (meji), Jigawa (ẹyọkan).

 

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.