Take a fresh look at your lifestyle.

ÀKÍYÈSÍ: Igbákejì Ààrẹ ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí kò dupò gómìnà mọ́ lábẹ́ PDP

Igbákejì Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tẹ́lẹ̀ rí, Ike Ekweremadu ti sọ pé òun kò ní kópa nínú ìbò alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ẹgbẹ́ People's Democratic Party ti ìpínlẹ̀ Ẹnúgu tí yóò wáyé ní Ọjọ́bọ̀,ọjọ́ kẹẹ̀dọ́gbọ̀n, Oṣù Karùn…

Ìdẹ̀ra déé

Ìjọba Nàìjíríà ti gba ẹgbàajì lé ní- irínwó  àwọn òògùn àjẹsára ààrùn còrónà ti Johnson & Johnson  tí ìjọba àti àwọn ènìyàn Sípènì fi tọrẹ fún Nàìjíríà. Nigba ti o n sọrọ nibi ayẹyẹ ranpẹ, lati…

Wọ́n gbóríyìn fún Àwọn ọmọ-ogun márùn ún tó pàdánù ẹ̀mí wọn ní Bọ̀kíná Fasò

Àwọn ọmọ-ogun márùn ún àti ọgbọ̀n "àwọn oníjàgídíjàgan" ti pàdánù ẹ̀mí wọn níbi ìjà àriwá ní Bọ̀kíná Fasò lẹ́yìn tí àwọn ogunlọ́gọ̀ tí wọ́n fura sí bí ọlọ́tẹ́  kọlu ibùdó ológun ,gẹ́gẹ́ bí ọmọ-ogun náà ṣe…

2023: Àwọn olùdíje Ààrẹ Gúúsù Ìlà Oòrùn APC Ṣetán láti ṣàtìlẹ́yìn fún Olùdíje Ígbò

Àwọn olùdíje fún ipò ààrẹ láti ẹkùn Gúúsù ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ń ṣe àkóso ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress APC,  ti ṣe ìlérí láti ṣe àtìlẹyìn fún èyíkẹ́èyí olùdíje Gúúsù ìlà…

Ẹ gbé àwọn Òṣìṣẹ́ Ìlera Àyíká dìde Láti fòpin sí ìṣègbọ̀nsẹ̀ níta gbangba –…

Ìgbìmọ̀ Ìforúkọsílẹ̀ Àwọn òṣìṣẹ́ Ìlera Àyíkáa  Nàìjíríà, EHORECON, ti pè fún àtìlẹyìn gbogbo àwọn tí ó níí ṣe pẹ̀lú ààbò àyíká láti gbé Àwọn òṣìṣẹ́ wọn dìde lọ sí àwọn  agbègbè ìlú àti…

Nàìjíríà le jẹ́kan lára àwọn orílẹ̀-èdè tó dára jù lọ – Ọ̀sínbàjò

Igbákejì Ààrẹ Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò sọ pé Nàìjíríà ní gbogbo ohun tí ó gbà láti di ọ̀kan nínú àwọn orílẹ̀-èdè tó lágbára jù,ó rọ àwọn ará ìlú láti yan olórí tí ó dára jùlọ fún…
button