Sudan kásẹ̀ ìjọba Pàjáwìrì nílẹ̀
Alákòóso gbogbogbòò Sudan ti kásẹ̀, ìjọba pàjáwìrì lórílẹ̀-èdè náà lẹ́yìn ìfipágbàjọba Oṣù Kẹwàá nílẹ̀.
Awọn ọmọ Orile-ede naa tun fi ẹhonuhan lori ilodi si ifipa gbajọba awọn ologun ni ipari ọsẹ.
Awọn alaṣẹ…