Orílẹ̀-èdè South Áfíríkà ṣe Ìfilọ́lẹ̀ àjọ ìgbógunti Ìṣíwá Ní Dọ́bánù
Ọgọọgọ̀rún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Operation Dudula kóra wọn jọ ní òpópónà Dọ́bánù, tí wọ́n sì ń bèèrè pé kí ìjọba gbé ìgbésè tó lágbára láti kojú àwọn ọgọ́ọ́rọ àwọn ènìyàn tí ń ṣíkiri lọ́nà àìtọ́.
Awọn…