Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Ọ̀ṣínbàjò Ṣàbẹ̀wò sí Òndó,ó bá wọn kẹ́dùn

Igbákejì Ààrẹ orílè-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀ṣínbàjò ti Dé sí Ìpínlẹ̀ Òndó, gúúsù ìwọ oòrùn Nàìjíríà, ní ibi tí ìpànìyàn tó burúu àwọn olùjọ́sìn ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́  karùn ún,oṣù kẹfà,…

Igbákejì ààrẹ ń darí àpèjọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ àpapọ̀

Igbákejì Ààrẹ orílè-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò ń darí ìpàdé Ìgbìmọ̀ Aláse ìjọba àpapọ̀, èyítí ó bẹ̀rẹ̀ ní déédé agogo mẹ́wàá òwúrọ̀ Ọjọ́bọ̀, ní gbàngàn ìgbìmọ̀, ní ilé-iṣẹ́…

Tàìwánù tún tẹ̀ síwájú lórí ìjíròrò Ìṣòwò Pẹ̀lú Amẹ́ríkà

Tàìwánù sọ pé olórí olùdúnàádúrà ìṣòwò rẹ̀, John Deng, yóò tún tẹ̀ síwájú lórí  ìjíròrò  síi pẹ̀lú Amẹ́ríkà lórí ìṣòwò orílẹ̀-èdè méjééjì ní Ọjọ́bọ̀, lẹ́yìn tí wọ́n ti yọọ́ kúrò nínú ètò…

Ààrù onígbáméjì: NCDC kéde ọ̀kàn-d́ín-ní-òjì dín- ní- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ẃa Àwọn tí wọn…

Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀  láti Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣàkóso àjàkálẹ̀ Ààrùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NCDC),àwọn ènìyàn tó ti ju mẹ́rìnlé-láàdọ́ta lọ ni ààrùn onígbáméjì ti gbẹ̀míẹ̀. Aarun onigbameji, jẹ akoran igbẹ…
button