Gómìnà kéde ìṣọfọ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Òndó Fún Àwọn olùfaragbà
Gómìnà ìpínlẹ̀ Òndó ní Gúúsù-Iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, Olúwarótìmí Akérédolú ti pàsẹ fún gbogbo ilé, ohun èlò àti ibùgbé òṣìṣẹ́ láti ta àsìá Nàìjíríà ní ìdajì fún ọjọ́ méje ní ìyẹ́sí àwọn tó…