Take a fresh look at your lifestyle.

Ọjọ́ àyájọ́ ìfẹ̀jẹ̀ sílẹ̀: Ìgbìmọ̀ pè Fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí ètò Ẹ̀jẹ̀ ní…

Ìgbìmọ̀ tó ń ṣètò Ẹ̀jẹ̀ lórílẹ̀-èdè, ti pè fún Ìbáṣepọ̀ ìjọba àti Aládàáni lórí ètò ẹ̀jẹ̀ láti mú ìlọsíwájú bá kẹ́jè tí kò léwu wà lárọwọ́ tó lorilẹ-ede. Aṣoju Adari agba fun ajọ naa, Dokita Omale…

Olùdíje ipò Ààrẹ APGA Yan Alága ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ Bauchi tẹ́lẹ̀ rí gẹ́gẹ́ bí igbákejì

Olùdíje ààrẹ fún ẹgbẹ́ òṣèlú APGA, All Progressives Grand Alliance nínú ìdìbò ọdún 2023, Adájọ́ àgbà tẹ́lẹ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Peter Umeadi, ti yan gbajúgbajà olórí àwọn òṣìṣẹ́ nígbà kan rí,…

Ọjọ́ àyájọ́ ìjọba Tiwa-n-tiwa: Ìjọba Ògùn Yí Ìdájọ́ Ikú Padà Fún Àwọn ẹlẹ́wọ̀n Kan

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn, gúúsù iwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fọwọ́sí yíyí ìdájọ́ àwọn ẹlẹ́wọ̀n mẹ́fà tí wọ́n dá ẹjọ́ ikú fún sí ẹ̀wọ̀n ayérayé àti pé ó tún dá àwọn ẹlẹ́wọ̀n ogójì sílẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ara…

Ààrẹ Bùhárí kí ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí, Abdulsalami Abubakar kú ọjọ́ ìbí ọgọ́rin ọdún

Aarẹ Muhammadu Buhari ti ṣajọyọ fun ajagun fẹtinti Abdulsalami Abubakar, Olori orilẹ-ede nigba kan ri ati Alaga igbimọ ẹgbẹ alaafia, lori ọjọ ibi ọgọrin ọdun  rẹ, ni ọjọ kẹtala, Oṣu Keje,ọdun 2022. Ààrẹ, lórúkọ ìjọba àti ẹbí rẹ̀, ń dara…
button