Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-iṣẹ́ ológun Nàìjíríà fún Àwọn ẹgbẹ̀rin olùgbé Sókótó ní ìtọ́jú ọ̀fẹ́

Ilé-iṣẹ́ ọmọ ogun Nàìjíríà ikọ̀ kẹjọ ti fún àwọn ènìyàn tí ó ju ẹgbẹ̀rin lọ ní  agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Sifawa, Bodinga ati Denge-Shuni ní  Ìpínlẹ̀ Sókótó ní ìtọ́jú ọ̀fẹ́. Nigba ti o n sọrọ nibi ayẹyẹ naa,…

Àwọn ẹ̀ṣọ́ Ààrẹ ya bo àwọn oníjàgídíjàgan ní ìpínlẹ̀ Katsina

Ààrẹ ti ṣàlàyé ìṣẹ̀lẹ̀ ìbọn yínyìn ọjọ́ Ìṣẹ́gun  ní agbègbè Dutsinma, ní ìpínlẹ̀ Katsina, mọ́ àwọn ọkọ̀ tí ó ń gbé àwọn ikọ̀ ẹ̀ṣọ́ ààbo, ìlànà àti àwọn òṣìṣẹ́ oníròyìn ṣaájú  Ààrẹ Mùhámmádù…

2023:Olùdarí àgbà VON Ṣọ àsọtẹ́lẹ̀ Ìṣẹ́gun Tinúubú ní ìdá ọgọ́ta nínú ọgọ́rùn ún

Olùdarí Àgbà fún Voice of Nigeria, VON, Osita Okechukwu, sọ pé olùdíje fún ipò Ààrẹ ẹgbẹ́ All Progressives Congress, APC, Ọ̀gbẹ́ni Bọ́lá Tinúubú, yóò borí nínú ìdìbò ọdún 2023, ní ìdá ọgọ́ta nínú ogórùn ún.…
button