Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Àgbáyé Kàn Ṣé Ètò Ìdàgbàsókè Ní Ìpínlẹ̀ Taraba Àtí Adamawa

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 276

Àjọ Àgbáyé fún Ìṣípò ‘International Organisation For Migration IOM’, ẹ̀ká tí Nàìjíríà, sọ́ pé àwọn yóò mú ìlọsíwájú bá Ìdókó-òwò rẹ̀ lórí àwọn iṣẹ́ àkànṣe kàn láti dẹkùn àwọn rògbòdìyàn kí àdínkù lè bá òṣì, bí ìgbéga lé bá àwọn ènìyàn Ìpínlẹ̀ Taraba àtí Adamawa.

Alákóso IOM ní Nàìjíríà, Laurent de Boeck, sọ èyí ní Ọjọ́ Ẹtì ní Abuja níbí idasilẹ ìpele Kejì tí ìṣẹ́ àkànṣe tí àjọ náà èyí tí yóò tẹ̀síwájú lórí ìparí áàwọ̀.

Àdele Olùdarí àtí Alákóso Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àtí Àbala ìjọba tiwantiwa àti Iṣipo kiri, aṣojú Àjọ Yúrópù sí Nàìjíríà àti ECOWAS, Ọ̀gbẹ́ni Ruben Aguilera, sọ ìpinnu tí àjọ náà láti ṣé atilẹyin fún ìpẹ̀tù sí áàwọ̀ ní Nàìjíríà.

Gẹ́gẹ́ bí o tí sọ, ó tí ṣé dandan fún Ìdókó-òwò tó péye ní agbègbè ààbò orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

O sọ pé a tí gbé àwọn ìgbésẹ̀ láti ṣiṣẹ́ síwájú ní àwọn agbègbè Northwest, Northeast, Niger Delta ati Middle Belt.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button