Ìfipágbàjọba: Àkókò Tí Ń Súnmọ́ Bí Àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà Ṣé Ń Gbáradì
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ọjọ́ méje tí àwọn Olùdarí Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà fún àwọn ológun ní Orílẹ̀-èdè Niger tí ń súnmọ́. Àkókò ọjọ́ méje náà ní láti dá Ààrẹ Mohamed Bazoum tí wọ́n dìtẹ gbàjọba lọ́wọ́ rẹ̀ sílẹ̀ pàdà, bí àpá méjèèjì ṣé níṣẹ́ ṣé.
Ní irọlẹ ọjọ́ Àìkú tó kọjá yìí, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Ecowas kàn tí Ààrẹ Bola Tinubu ṣé olórí, so pé ọsẹ kàn ní àwọn ìjọba ológun náà ní látí dá Ìjọba tiwa-n-tiwa pàdà sípò tàbí kojú lílò àgbàrá.
Látí orí títí àwọn ibodè orílẹ̀-èdè náà, dórí pípa iná mọnamọna orílẹ̀-èdè náà láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ará àwọn ìjìyà tí orílẹ̀-èdè náà tí ń kojú.
ECOWAS tún sọ pé ṣeéṣe kí wọ́n ló àgbàrá àwọn ọmọ ogún àwọn orílẹ̀-èdè Ìwọ̀-oòrùn náà ní ìkẹyìn tí àwọn bá gbìyànjú gbogbo òun tó yẹ́.
Leave a Reply