Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ Ààrẹ pàtàkì kàn tí Mínísítà fún ètò ọrọ̀-àjé àtí ètò ìnáwó, Ọ̀gbẹ́ni Wale Edun dárí.
Ìgbìmọ̀ Pàtàkì náà ní wọ́n gbé kálẹ̀ látí ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ojúṣe tí ṣí ṣé àtúnyẹwò àtí iṣé àyẹwò àwọn ìlànà ètò ìnáwó tó wà àtí àwọn ìlànà ìmúlò tí àwọn ètò ídókó-owó àwùjọ.
Èyí ní látí ríi dájú ètò ìlànà ìnáwó náà.
Àtúnyẹwò tí ètò náà tún jẹ́ pẹ̀lú ìyípadà àlàyé sí àwọn ìlànà tí n ṣé ìtọ́sọ́nà imuṣé àwọn ètò tí nlọ́ síwájú.
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mìíràn tí ìgbìmọ̀ náà ni; Mínísítà tí Ìlera àtí ètò àwùjọ – Ali Pate, Mínísítà fún Ìṣúná àtí Ètò Ìṣòwò – Ọmọ Ẹgbẹ́, Atiku Bagudu , Mínísítà fún ètò ìròyìn àti Àlàyé Orilẹ-ede – Ọmọ Ẹgbẹ́, Idris Mohammed.
Mínísítà fún Àwọn Ìbáraẹnisọ̀rọ̀, oún ọtún àtí ‘Digital Economy’ – Ọmọ Ẹgbẹ́, Bosun Tijani àtí Mínísítà tí Ìpínlẹ̀ fún Àwọn ọdọ – ọmọ ẹgbẹ́