Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Bú Ìyìn Fún Awọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 246

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Ahmed Tinubu, ṣé àpèjúwe Òṣìṣẹ́ ìjọba gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rọ́ ìṣètò àti ìmúṣẹ ṣé àwọn ìlànà àti ètò ìjọba fún ìdàgbàsókè ètò ọrọ̀ ajé lápapọ̀ orílẹ̀-èdè náà.

Ààrẹ Tinubu sọ ọrọ̀ yìí níbí ọsẹ ayẹyẹ àwọn Òṣìṣẹ́ ìjọba ní Olú-ìlú Abùjá, Nàìjíríà.

Àkọwé Ìjọba tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, George Akume tó ń ṣoju Ààrẹ fí kún pé, Ààrẹ ní ìgbàgbọ́ nínú àwọn òṣìṣẹ́ wọnyí fún ìtèsíwájú àtí àgbéga.

Ààrẹ Tinubu gbóríyìn fún ọ̀gá àgbà òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀, Folashade Yemi-Esan fún ìríran rẹ̀ nípa ètò iṣẹ́ ìjọba túntún àti ìpinnu rẹ̀ láti ṣé bẹ́ẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button