Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Ṣàjọyọ̀ Pẹ̀lú Alákòóso Túntún Tí Ilé-iṣẹ́ Owó Ìdókòwò Ojú-ọjọ́

0 271

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí gbóríyìn fún Ìyááfín Tariye Gbadegesin lórí ipò túntún rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Alákóso Àgbà (CEO) tí Àwọn Owó Ídókó-owó Ojú-ọjọ́.

Tariye Gbadegesin, tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà, tí dì ọmọ Adúláwọ̀ àkọ́kọ́ tí yóò wà nípò yìí gẹ́gẹ́ bí Alákóso tí Ilé-iṣẹ́ Owó Ídókó-owó Ojú-ọjọ́ (CIF). Ṣùgbọ́n yóò gbá ipò túntún náà ní Oṣù Kẹ́ta ní ọdún 2024.

Ààrẹ náà sọ̀rọ̀ náà lórí ìkànnì X rẹ̀ (èyítí a mọ̀ tẹ́lẹ̀ bí Twitter) pé ipò Tariye kìí ṣé àṣeyọrí tí ará rẹ̀ nìkàn, ṣùgbọ́n ṣé àfihàn ipá Nàìjíríà lágbayé.

CIF ní wọ́n dá sílè ní ọdún 2008 látí ṣé koriya fún ìṣúná ìnáwó fún èròngbà kékeré, ìṣàkóso ìdàgbàsókè Ojú-ọjọ́ ní ìwọn àtí pé wọ́n sì pá tó ìyè owó $64 bílíọ̀nù titi dì onì.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button