Take a fresh look at your lifestyle.

Ohun tó wù yín, ni kí ẹ wí, ètò ìdìbò ọdún 2023 yóò wáyé ní Nàíjíríà – Lai Mohammed

0 260

Minisita fun eto iroyin ati asa lorilẹ ede Naijiria,Lai Mohammed  ti ni ki awọn ọmọ orilẹ ede Naijiria ati ilẹ̀ agbaye fọkan balẹ pe eto idibo ọdun 2023  lorilẹ ede Naijiria yoo lọ ní irọwọ ati irọsẹ.

Minisita sóró yii lasiko to n ba awón akóroyin sóró léyin ipade igbimó alasé to waye  nile aaré to wa niluu Abuja.Minisita tésiwaju  pe , iró ati ahesó óró patapata gbaa ni awón kan n só pe eto iddibo ódun 2023 yoo mu wahala ati idiwó dani nitori awón ipenija to n dojuko orilé ede yii nipa eto aabo.

.Lai Mohammed wa gbosuba fun awón ẹ̀sọ́ alaabo fun gudu gudu meje  , yaya mẹfa lati mojuto eto aaboo ati alaafia lorilẹ ede Naijiria.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button