Take a fresh look at your lifestyle.

Fíìmù Alárinrin “Aníkúlápò” Yòó Lulẹ̀ Gbà Láìpẹ́- Kúnlé Afọláyan

0 250

Gbajúgbajà òsèré fíìmù ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Kúnlé Afọláyan ti sọ pé fíìmù alárinrin rẹ̀ “Aníkúlapò” yóò jáde bí ọmọ tuntun nínú Oṣù Kẹsàn án ọdun yìí.
Gẹ́gẹ́bí òṣèré fíìmù náà, ẹnití ó sọ èyí di mímọ̀ lórí ẹ̀rọ Instagírámù rẹ̀ ní ọjọ́ Ìsẹ́gun wípé òun óò ṣe ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ lórì @naijaonnetflix ní ọjọ́ ọgbọ̀n Oṣu Kẹsàn án ọdún ỳíi lẹ́yìn tí Afọláyan ti kéde fọ́tò yíyà àkọ́kọ́ rẹ̀ ní oṣù kejì ní Ị̀pínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
ÀwỌn gbajúgbajà òsèré bíi, Sọla Sóbọ̀wálé, Bimbọ Ademoye, Hakeem Kae-Kazim, Taiwo ‘Ogogo’ Hassan, Aisha Lawal abbl ni wọ́n kópa nínú fíìimù alárinrin náà.

 

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button