Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Bùhárí búra fún àwọn akọ̀wé aláṣẹ mẹ́ta

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 249

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí ti búra fún àwọn akọ̀wé aláṣẹ mẹ́ta kan.

Iṣẹlẹ naa waye ni Ọjọru, ni gbangan Igbimọ ni Villa,ibudo aarẹ,ni ilu Abuja.

Awọn Akọwe Alaṣẹ Tuntun naa n: Lydia Jafiya lati Ipinlẹ Adamawa; Udom Ekenam lati Ipinlẹ Akwa Ibom ati Farouk Yusuf Yabo lati Ipinlẹ Sokoto.

Lara awọn ti wọn wa nibi ibura naa ni :akọwe ijoba apapo, Boss Mustapha, Ọga agba fun awọn oṣiṣẹ  Aarẹ, Ọjọgbọn Ibrahim Gambari ati Olori awọn oṣiṣẹ ijọba apapọ, Dokita Fọlashade Yẹmi-Ẹsan.

Aarẹ dari ipade Igbimọ Alase apapọ, eyiti o bẹrẹ lẹsẹkẹsẹ ti wọn pari ayẹyẹ ibura naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button