Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Lórí síso Àwọn ilé-iṣẹ́ Ìjọba pọ̀
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ilé-̀ìgbìmọ̀ Aṣojú lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ṣe ìfílọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ pàjáwìrì kan láti ṣe ìwádìí Ìṣẹ́pọ̀ àwọn iṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Olori ile igbimọ aṣoju, Hon. Fẹmi Gbajabiamila, ẹni ti o ṣe ifilọlẹ igbimọ naa, sọ pe igbimọ naa ni erongba wọn ni lati din iye owo isejọba ku, ati lati dena aṣeju.
O sọ pe, ijọba ti ṣe akiyesi pe awọn ile-iṣẹ ijọba kan wa ti wọn n ṣe iṣe kannan, eyi ti o fa airisẹ ṣe.
Leave a Reply