Wọ́n ti ko àwọn èrò arinrinajo inú ọkọ̀ ojú-irin tó farapa ní Kaduna láti Abuja ní òwúrọ̀ yìí. Àwọn òṣìṣẹ́ ààbò, àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ tí ó ń ṣe ìtọ́jú pàjáwìrì ní ìpínlẹ̀ Kaduna (SEMA) àti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Red Cross Nàìjíríà ni ó sisẹ́ náà.
Àwọn arìnrìn-àjò tí ó farapa ni a ti gbé lọ sí àwọn ilé-ìwòsàn.
A le ranti pe, oko oju irin ti o n lọ si Kaduna lati Abuja ti o ko awọn arinrin ajo to to ojì-din-lẹwá d́in ńi ẹgbẹ́rún (970) ni wọn kọlu ni ọjọ Aje, lẹba ọna Rijana-Katere ni ipinlẹ Kaduna.
Leave a Reply