Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Super Eagles, Justice Christopher di olóògbé

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 287

Agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tẹ́lẹ̀ rí, Justice Christopher di olóògbé,ẹni ogójì ọdún níí ṣe.

Andrew Randa, oṣiṣẹ oniroyin ti orilẹ-ede fun ikọ ọkunrin ti ko ju ogun ọdun lọ,lo kede iku Christopher ninu tiwiti rẹ kan ni Ọjọbọ.

Gege bi ọrọ Randa, Christopher jade laye laarọ ọjọ aje ni inu yara itura rẹ  ni Jos, ni ipinlẹ Plateau.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button