Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjàǹbá Iná Àbújá: Mínísítà fún ọmọnìyàn kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn olùfaragbá

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 274

Mínísítà fún ètò ọmọnìyàn, ètò  àjálù àti ìdàgbàsókè àwùjọ, Sadiya Umar Farouq ti kẹ́dùn lórí ìpàdánù ọjà àti dúkìá tí ó tó bílíọ̀nù owó dọ́là Náírà, nínú ìṣẹ̀lẹ̀ iná tó wáyé ní ilé ìtajà gbajúgbajà, Next Cash and Carry, ní ìlú Àbújá.

Minisita naa bẹnu atẹ lu bi   ajalu ina ni orilẹ-ede naa ṣe n waye lera ,o si  rọ awọn eniyan ṣọra ati lati yago fun awọn iṣẹlẹ iwaju.

Iṣẹlẹ ti o waye ni ọjọ bọkisin naa ṣe Umar Farouq  laanu pupọ  ti paṣẹ fun Ile-iṣẹ Itọju Pajawiri  Orilẹ-ede, NEMA, lati ṣe gbogbo  iranlọwọ ti wọn ba le ṣe fun wọn ni ọjọ ijanba ina naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button