Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Tí Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Túntún

313

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara, tí ṣé ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ túntún tí yóò máa ṣé àkóso tí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí Ìpínlẹ̀ Kwara (KWASU).

Nígbàtí o n ṣé ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ náà, Ìgbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, Ọ̀gbẹ́ni Kayode Alabi rántí pé ní àwọn ọjọ́ díẹ̀ sẹyìn ní Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tí fọwọ́sí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ sí ìgbìmọ̀ alákóso tí Ilè-ẹ̀kọ́ gíga tí Ìpínlẹ̀ Kwara (KWASU).

Nínú àwọn ọrọ̀ Kọmíṣọ́nà fún ètò Ilè-ẹ̀kọ́ gíga, Dókítà Mary Arinde ṣé àkíyèsí pé ìfilọ́lẹ̀ náà jẹ́ àmì-iṣẹ́ pàtàkì kàn tó ṣé àfihàn ìpinnu ìjọba ìpínlẹ̀ náà sí ìlọsíwájú ètò ẹ̀kọ́ tí ilé-ìwé gíga àtí ìwádìí.

Nígbà tó ń fèsì lórúkọ ìgbìmọ̀ túntún náà, alága ìgbìmọ̀ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Abdulganiyu Ambali, tó tí jẹ́ ìgbákejì Ọgá àgbà Ilé-ìwé gíga Yunifásítì tí Ilorin fí im’oore rẹ̀ hàn sí Gómìnà fún fífi àrà balẹ̀ yàn àwọn ọmọ ẹgbẹ́ látí ṣé amojuto pẹ̀lú ìmọ àti oyè, òun ìrírí wọ́n fún ìdàgbàsókè ètò-ẹ̀kọ́ ní ìpínlè Kwara.

Comments are closed.

button