Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sokoto gbóríyìn fún iṣẹ́ Àkànṣe USAID

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 195

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sokoto, Ahmed Aliyu ti gbóríyìn fún àgbékalẹ̀ ìpínlẹ̀ sí ìpínlẹ̀ ti USAID, láti ri pé ètò àti ìlànà ní ìpínlẹ̀ náà dá lórí òdodo àti ìfọkànsìn.

Gomina Aliyu ṣe igboriyin yi nibi ipade gbọngan ilu ki agbekalẹ isuna ọdun 2024 to waye ni ipinlẹ Sokoto.

Gẹgẹ bi o ṣe sọ, iṣẹ akanṣe ipinlẹ si ipinlẹ ko ipa ribiribi lori ekọ, iwosan, iṣemọtoto omi ati iṣetọju ara laarin awọn miiran.

O wa dupẹ lọwọẹgbẹ naa ti o si n mu dawọn loju pe ijọba yoo tẹsiwaju lati fọwọsowọpọ pelu iṣẹ akanṣe ipinlẹ si ipinlẹ fun ilọsiwaju ibiafede ipinlẹ naa

Gomina Aliyu wa fikun un pe ijọba ohun yoo maa gbe owo to to silẹ lati ri pe awọn eto ipinlẹ wa si imuṣẹ fun idagbasoke ipinlẹ

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button