Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àgbábọ́ọ̀lù Super Eagles tí bẹ̀rẹ̀ sí dé ibudó ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù náà ní ìlú Uyo ṣáájú ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ ìdíje ife àgbáyé tí ọdún 2026 pẹ̀lú Lesotho àtí Zimbabwe, lẹsẹẹsẹ.
Jose Peseiro tó jẹ́ olukọni àgbà fún ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà tí yàn àwọn àgbábọ́ọ̀lù mẹ́tàlélogún fún ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ náà tí yóò wáyé ní ọjọ́ kẹrindinlogun oṣù Kejìlá àti ọjọ́ kọkandinlogun oṣù Kejì, ní Uyo àti Kigali.
Anticipate! Road to 🇺🇸 🇨🇦 🇲🇽 begins tomorrow. We can’t wait, who else can’t? Where will you be watching from? #soarsupereagles #fifa2026worldcupqualifiers #letsdoitagain pic.twitter.com/nKAv99ckGn
— 🇳🇬 Super Eagles (@NGSuperEagles) November 15, 2023
Arrival of more Eagles #soarsupereagles #letsdoitagain #fifa2026worldcupqualifiers pic.twitter.com/98KdgdFJBV
— 🇳🇬 Super Eagles (@NGSuperEagles) November 14, 2023
Preparation kicks off. Welcome Amas Obasogie @NathanTella_11 #soarsupereagles #letsdoitagain #fifa2026worldcupqualifiers pic.twitter.com/kmZyTONfO5
— 🇳🇬 Super Eagles (@NGSuperEagles) November 14, 2023
Pẹ̀lú ìrètí pé gbogbo àwọn àgbábọ́ọ̀lù tí a pè yóò wà ní ibùdó lóní fún ìbẹrẹ ikẹkọ àti igbaradi eré pípé.
Leave a Reply