Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn tó nííṣe ṣe àyẹ́síi ìgbé ayé àwọn àgbẹ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 249

Owó káríayé fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn, IFAD-Ètò ìrànlọ́wọ́ àpapọ̀ iyì fún ìdàgbàsókè, VCDP, ti sọ pé ọdún mẹ́sàn án ti òhun ti wà ní ìpínlẹ̀  Ebonyi, Gúsù iwọ̀ oòrùn Nàìjíríà, ti ran ìgbé ayé àwọn àgbẹ̀ tó jàǹfààní náà lọ́wọ́ gidi gan ni.

Alakoso eto, NPC, ti IFAD-VCDP, lorilẹ-ede Dokita Fatima Aliyu, ṣe ikede yii ni Abakaliki lasiko pinpin awọn ẹrọ iṣiṣẹ eto ọgbin ati awọn kẹmika ohun ọgbin fun awọn to janfaani ni ipinlẹ naa.

Aliyu, ti Ọgbẹni Gidado Bello, oludamọran lori orisun awọn oṣisẹ IFAD-VCDP, ni olu ile-isẹ Abuja, soju sọ pe iru iranlọwọ naa ni o ṣe okunfa ironilagbara to dara to dangajia, ipese ounjẹ ati aabo ni ilu naa.

O wa sọ pe awọn ẹrọ iṣiṣẹ naa yoo jẹ ‘ibusọ orisun eto ọgbin’ ti awọn agbẹ ti le mu ohun ti wọn ba le mu lati ṣatunṣe lori jijẹ mimu wọn.

Gomina Francis Nwifuru, ninu afiranṣẹ rẹ, wa sọ pe IFAD ti jẹ irinṣẹ pataki si idagbasoke ti ijọba ti ni lori iranlọwọ fun awọn agbẹ ni ipinlẹ naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button